Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kabiyesi, bí mo ti ń lọ lọ́nà lọ́sàn-án gangan, mo rí ìmọ́lẹ̀ láti ọ̀run tí ó mọ́lẹ̀ ju ti oòrùn lọ, tí ó tàn yí èmi ati àwọn tí ń bá mi lọ ká.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 26:13 ni o tọ