Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 26:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń lọ láti ilé ìpàdé kan dé ekeji, mo sì ń jẹ wọ́n níyà, bóyá wọn a jẹ́ fẹnu wọn gbẹ̀ṣẹ̀. Ẹ̀tanú náà pọ̀ sí wọn tó bẹ́ẹ̀ tí mo fi lé wọn dé ìlú òkèèrè pàápàá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 26:11 ni o tọ