Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Paulu dé, àwọn Juu tí wọ́n wá láti Jerusalẹmu tò yí i ká, wọ́n ń ro ẹjọ́ ńláńlá mọ́ ọn lẹ́sẹ̀ lọ́tùn-ún lósì, bẹ́ẹ̀ ni kò sí èyí tí ó lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ ninu gbogbo ẹjọ́ tí wọ́n rò.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 25:7 ni o tọ