Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Agiripa bá wí fún Fẹstu pé, “Èmi fúnra mi fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu ọkunrin náà.”Fẹstu dáhùn ó ní, “Ẹ óo gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu rẹ̀ lọ́la.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 25:22 ni o tọ