Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkan kò rí mi kí n máa bá ẹnikẹ́ni jiyàn ninu Tẹmpili. Bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kò rí mi pé mo kó àwọn eniyan jọ láti dá rúkèrúdò sílẹ̀, ìbáà ṣe ninu ilé ìpàdé ni tabi níbikíbi láàrin ìlú.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 24:12 ni o tọ