Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí àwọn Sadusi sọ pé kò sí ajinde, bẹ́ẹ̀ ni kò sí angẹli tabi àwọn ẹ̀mí; ṣugbọn àwọn Farisi gbà pé mẹtẹẹta wà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 23:8 ni o tọ