Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu dáhùn pé, “Ará, n kò mọ̀ pé Olórí Alufaa ni. Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ sọ̀rọ̀ burúkú sí aláṣẹ àwọn eniyan rẹ.’ ”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 23:5 ni o tọ