Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:34-35 BIBELI MIMỌ (BM)

34. Gomina ka ìwé náà. Ó wá wádìí pé apá ibo ni Paulu ti wá. Wọ́n sọ fún un pé ní agbègbè Silisia ni.

35. Ó bá sọ fún un pé, “N óo gbọ́ ẹjọ́ rẹ nígbà tí àwọn tí ó fi ẹjọ́ rẹ sùn náà bá dé.” Ó bá pàṣẹ pé kí wọ́n máa ṣọ́ Paulu ní ààfin Hẹrọdu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 23