Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń dè é mọ́lẹ̀ láti máa nà án, Paulu bi balogun ọ̀rún tí ó dúró pé, “Ẹ̀tọ́ wo ni ẹ níláti na ọmọ-ìbílẹ̀ Romu láì tíì dá a lẹ́jọ́?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 22:25 ni o tọ