Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu dáhùn ó ní, “Juu ni mí, ará Tasu ní ilẹ̀ Silisia. Ọmọ ìlú tí ó lókìkí ni mí. Gbà mí láàyè kí n bá àwọn eniyan sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:39 ni o tọ