Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti fẹ́ mú Paulu wọ inú àgọ́ ọmọ-ogun, ó sọ fún ọ̀gágun pé, “Ṣé kò léèwọ̀ bí mo bá bá ọ sọ nǹkankan?”Ọ̀gágun wá bi í léèrè pé, “O gbọ́ èdè Giriki?

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:37 ni o tọ