Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà tí a dágbére fún wọn tán, ọkọ̀ ṣí. A wá lọ tààrà sí Kosi. Ní ọjọ́ keji a dé Rodọsi. Láti ibẹ̀ a lọ sí Patara.

2. A rí ọkọ̀ ojú omi kan níbẹ̀ tí ó fẹ́ sọdá lọ sí Fonike. Ni a bá wọ̀ ọ́, ọkọ̀ bá ṣí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21