Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn n kò ka ẹ̀mí mi sí ohunkohun tí ó ní iye lórí fún ara mi. Ohun tí mò ń lépa ni láti parí iré ìje mi ati iṣẹ́ tí mo gbà lọ́wọ́ Oluwa mi Jesu, èyí ni pé kí n tẹnu mọ́ ìyìn rere oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:24 ni o tọ