Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù àwọn onigbagbọ wá ń ba gbogbo eniyan. Ọpọlọpọ ni iṣẹ́ ìyanu ati iṣẹ́ abàmì tí a ti ọwọ́ àwọn aposteli ṣe.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:43 ni o tọ