Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii tí a ti gbé e ka ọwọ́ ọ̀tún Ọlọrun, ó ti gba ìlérí Ẹ̀mí Mímọ́ láti ọ̀dọ̀ Baba, ó wá tú u jáde. Ohun tí ẹ̀ ń rí, tí ẹ sì ń gbọ́ nìyí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:33 ni o tọ