Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Dafidi sọ nípa rẹ̀ pé,‘Mo rí Oluwa níwájú mi nígbà gbogbo,ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún minítorí náà ohunkohun kò lè dà mí láàmú.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:25 ni o tọ