Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:39-41 BIBELI MIMỌ (BM)

39. Bí ẹ bá tún ní ọ̀rọ̀ mìíràn tí ó jù yìí lọ, a óo máa yanjú rẹ̀ ní ìgbà tí a bá ń ṣe ìpàdé.

40. Nítorí bí a ò bá ṣọ́ra, a óo dé ilé ẹjọ́ fún ìrúkèrúdò ọjọ́ òní, kò sì sí ohun tí a lè sọ pé ó fà á bí wọ́n bá bi wá.”

41. Lẹ́yìn tí ó ti sọ báyìí tán, ó tú àwọn eniyan náà ká.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 19