Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wá rí i, ẹ tún ti gbọ́ pé kì í ṣe ní Efesu nìkan ni, ṣugbọn ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ pé ní gbogbo Esia ni Paulu yìí ti ń yí ọ̀pọ̀ eniyan lọ́kàn pada. Ó ní àwọn ohun tí a fọwọ́ ṣe kì í ṣe oriṣa!

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 19:26 ni o tọ