Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni ọkunrin tí ẹ̀mí burúkú wà ninu rẹ̀ bá fò mọ́ wọn; ó gbé ìjà ńlá kò wọ́n, ó sì ṣẹgun gbogbo wọn, ó ṣe wọ́n léṣe tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi sá jáde ninu ilé náà ní ìhòòhò, tàwọn ti ọgbẹ́ lára.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 19:16 ni o tọ