Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀ pẹlu ìgboyà ninu ilé ìpàdé àwọn Juu. Nígbà tí Pirisila ati Akuila gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, wọ́n mú un, wọ́n túbọ̀ fi ọ̀nà Ọlọrun yé e yékéyéké.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:26 ni o tọ