Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:14-16 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Bí Paulu ti fẹ́ lanu láti fèsì, Galio sọ fún àwọn Juu pé, “Ẹ̀yin Juu, bí ó bá jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ kan tabi ọ̀ràn burúkú kan ni ẹ mú wá, ǹ bá gbọ́ ohun tí ẹ ní sọ;

15. ṣugbọn tí ó bá jẹ́ àríyànjiyàn nípa àwọn ọ̀rọ̀ tabi orúkọ, tabi òfin yín, ẹ lọ rí sí i fúnra yín. N kò fẹ́ dá irú ẹjọ́ bẹ́ẹ̀.”

16. Ni ó bá lé wọn kúrò ní kóòtù.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18