Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Galio di gomina Akaya, àwọn Juu fi ohùn ṣọ̀kan láti dìde sí Paulu. Wọ́n bá mú un lọ sí kóòtù níwájú Galio.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:12 ni o tọ