Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:25-27 BIBELI MIMỌ (BM)

25. A ti wá pinnu, gbogbo wa sì fohùn sí i, a wá yan àwọn eniyan láti rán si yín pẹlu Banaba ati Paulu, àwọn àyànfẹ́ wa,

26. àwọn tí wọ́n ti fi ẹ̀mí wọn lélẹ̀ nítorí orúkọ Oluwa wa Jesu Kristi.

27. Nítorí náà a rán Juda ati Sila, láti fẹnu sọ ohun kan náà tí a kọ sinu ìwé fun yín.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 15