Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu ati Banaba pẹ́ níbẹ̀. Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ní gbangba, ẹ̀rù kò sì bà wọ́n nítorí wọ́n gbójú lé Oluwa tí ó jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ nípa iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu tí ó ń ti ọwọ́ wọn ṣe.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 14:3 ni o tọ