Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 14:23-25 BIBELI MIMỌ (BM)

23. Wọ́n yan àgbà ìjọ fún wọn ninu ìjọ kọ̀ọ̀kan. Nígbà tí wọ́n ti gbadura, tí wọ́n sì ti gbààwẹ̀, wọ́n fi wọ́n lé ọwọ́ Oluwa tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ wọn lé.

24. Wọ́n wá gba Pisidia kọjá lọ sí Pamfilia.

25. Nígbà tí wọ́n ti waasu ìyìn rere ní Pega, wọ́n lọ sébùúté ní Atalia.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 14