Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:29-31 BIBELI MIMỌ (BM)

29. Nígbà tí wọ́n ti parí ohun gbogbo tí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé yóo ṣẹlẹ̀ sí i, wọ́n sọ̀ ọ́ kalẹ̀ láti orí igi agbelebu, wọ́n tẹ́ ẹ sinu ibojì.

30. Ṣugbọn Ọlọrun jí i dìde kúrò ninu òkú.

31. Fún ọpọlọpọ ọjọ́ ni ó fi ara hàn fún àwọn tí wọ́n bá a wá sí Jerusalẹmu láti Galili. Àwọn ni ẹlẹ́rìí fún gbogbo eniyan pé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ rí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13