Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli náà sọ fún un pé, “Di ìgbànú rẹ, sì wọ sálúbàtà rẹ.” Peteru bá ṣe bí angẹli náà ti wí. Angẹli yìí tún sọ fún un pé, “Da aṣọ rẹ bora, kí o máa tẹ̀lé mi.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 12:8 ni o tọ