Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí Hẹrọdu pupọ sí àwọn ará Tire ati Sidoni. Àwọn ará ìlú wọnyi bá fi ohùn ṣọ̀kan, wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Wọ́n tu Bilasitu tíí ṣe ìjòyè ọba tí ó ń mójútó ààfin lójú, wọ́n ń bẹ̀bẹ̀ pé kí ọba má bínú sí àwọn nítorí láti ilé ọba ni wọ́n ti ń rí oúnjẹ jẹ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 12:20 ni o tọ