Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹẹkeji ohùn náà tún wá láti ọ̀run. Ó ní, ‘Ohunkohun tí Ọlọrun bá ti sọ di mímọ́, ìwọ kò gbọdọ̀ pè é ní aláìmọ́ mọ́.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 11:9 ni o tọ