Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji, bí wọ́n ti ń bá ìrìn àjò wọn lọ, tí wọ́n súnmọ́ Jọpa, Peteru gun òkè ilé lọ láti gbadura ní nǹkan agogo mejila ọ̀sán.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:9 ni o tọ