Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii wá rán àwọn kan lọ sí Jọpa, kí wọn lọ pe ẹnìkan tí ń jẹ́ Simoni, tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Peteru, kí ó wá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:5 ni o tọ