Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kì í ṣe àgọ́ tí a fi ọwọ́ kọ́ ni Kristi wọ̀ lọ, èyí tíí ṣe ẹ̀dà ti àgọ́ tòótọ́. Ṣugbọn ọ̀run gan-an ni ó wọ̀ lọ, nisinsinyii ó wà níwájú Ọlọrun nítorí tiwa.

Ka pipe ipin Heberu 9

Wo Heberu 9:24 ni o tọ