Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

mélòó-mélòó ni ẹ̀jẹ̀ Kristi, tí ó fi ara rẹ̀ rú ẹbọ tí kò lábùkù sí Ọlọrun nípa Ẹ̀mí ayérayé, yóo wẹ ẹ̀rí-ọkàn wa mọ́ kúrò ninu iṣẹ́ tíí yọrí sí ikú, tí yóo sì fi ṣe wá yẹ fún ìsìn Ọlọrun alààyè.

Ka pipe ipin Heberu 9

Wo Heberu 9:14 ni o tọ