Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 9:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Kristi ti dé, òun sì ni Olórí Alufaa àwọn ohun rere tí ó wà. Ó ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀ ninu àgọ́ tí ó pé tí ó sì tóbi ju ti àtijọ́ lọ, àgọ́ tí a kò fi ọwọ́ kọ́, tí kì í sì í ṣe ti ẹ̀dá ayé yìí.

Ka pipe ipin Heberu 9

Wo Heberu 9:11 ni o tọ