Kì í ṣe irú majẹmu tí mo bá àwọn baba wọn dání ọjọ́ tí mo fà wọ́n lọ́wọ́ jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti.Nítorí wọn kò pa majẹmu mi mọ́,mo bá kẹ̀yìn sí wọn.