Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì yóo sí ìdí tí ẹnìkan yóo fi kọ́ aládùúgbò rẹ̀ tabi arakunrin rẹ̀, pé,‘Mọ Oluwa.’Nítorí pé gbogbo wọn ni wọn óo mọ̀ mí,ohun tí ó ṣẹ̀ láti orí àwọn mẹ̀kúnnù inú wọn títí dé orí àwọn eniyan pataki pataki.

Ka pipe ipin Heberu 8

Wo Heberu 8:11 ni o tọ