Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Kókó ohun tí à ń sọ nìyí, pé a ní irú Olórí Alufaa báyìí, ẹni tí ó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún ìtẹ́ ọlá ńlá ní ọ̀run.

Ka pipe ipin Heberu 8

Wo Heberu 8:1 ni o tọ