Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, bí ó bá jẹ́ pé ètò iṣẹ́ alufaa ti ìdílé Lefi kò ní àbùkù, tí ó sì jẹ́ pé nípa rẹ̀ ni àwọn eniyan fi gba òfin, kí ló dé tí a fi tún ṣe ètò alufaa ní ìgbésẹ̀ Mẹlikisẹdẹki, tí kò fi jẹ́ ti Aaroni?

Ka pipe ipin Heberu 7

Wo Heberu 7:11 ni o tọ