Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Mẹlikisẹdẹki yìí jẹ́ ọba Salẹmu ati alufaa Ọlọrun Ọ̀gá Ògo. Òun ni ó pàdé Abrahamu nígbà tí Abrahamu ń pada bọ̀ láti ojú-ogun lẹ́yìn tí ó bá ọba mẹrin jà, tí ó sì pa wọ́n ní ìpakúpa. Ó bá súre fún Abrahamu.

Ka pipe ipin Heberu 7

Wo Heberu 7:1 ni o tọ