Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹnikẹ́ni tí a bá yàn láàrin àwọn eniyan láti jẹ́ olórí alufaa, a yàn án bí aṣojú àwọn eniyan níwájú Ọlọrun, kí ó lè máa mú àwọn ọrẹ ati ẹbọ fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn wá siwaju Ọlọrun.

Ka pipe ipin Heberu 5

Wo Heberu 5:1 ni o tọ