Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, dandan ni kí òun alára jọ àwọn arakunrin rẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà, kí ó lè jẹ́ Olórí Alufaa tí ó láàánú, tí ó sì ṣe é gbójú lé nígbà tí ó bá ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀ níwájú Ọlọrun fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ àwọn eniyan.

Ka pipe ipin Heberu 2

Wo Heberu 2:17 ni o tọ