Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọ̀kan ni ẹni tí ó ń ya eniyan sí mímọ́ ati àwọn eniyan tí ó ń yà sí mímọ́ jẹ́, nítorí náà ni Jesu kò fi tijú láti pè wọ́n ní arakunrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Heberu 2

Wo Heberu 2:11 ni o tọ