Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 12:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, níwọ̀n ìgbà tí ẹ ti gba ìjọba tí kò ṣe é mì, ẹ jẹ́ kí á dúpẹ́. Ẹ jẹ́ kí á sin Ọlọrun bí ó ti yẹ pẹlu ọ̀wọ̀ ati ẹ̀rù;

Ka pipe ipin Heberu 12

Wo Heberu 12:28 ni o tọ