Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 12:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí wọ́n rí bani lẹ́rù tóbẹ́ẹ̀ tí Mose fi sọ pé, “Ẹ̀rù ń bà mí! Gbígbọ̀n ni gbogbo ara mi ń gbọ̀n látòkè délẹ̀.”

Ka pipe ipin Heberu 12

Wo Heberu 12:21 ni o tọ