Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa igbagbọ ni a fi mú Enọku kúrò ní ayé láìjẹ́ pé ó kú. Ẹnikẹ́ni kò rí i mọ́ nítorí pé Ọlọrun ti mú un lọ. Nítorí kí ó tó mú un lọ, Ìwé Mímọ́ sọ nípa rẹ̀ pé, “Ó ṣe ohun tí ó wu Ọlọrun.”

Ka pipe ipin Heberu 11

Wo Heberu 11:5 ni o tọ