Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 11:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa igbagbọ, wọ́n ṣẹgun ilẹ̀ àwọn ọba, wọn ṣiṣẹ́ tí òdodo fi gbilẹ̀, wọ́n rí ìlérí Ọlọrun gbà. Wọ́n pa kinniun lẹ́nu mọ́.

Ka pipe ipin Heberu 11

Wo Heberu 11:33 ni o tọ