Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 10:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà mìíràn wọ́n fi yín ṣẹ̀sín, wọ́n jẹ yín níyà, àwọn eniyan ń fi yín ṣe ìran wò. Nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, ẹ dúró láì yẹsẹ̀ pẹlu àwọn tí wọ́n ti jẹ irú ìyà bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Heberu 10

Wo Heberu 10:33 ni o tọ