Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 10:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí á máa rò nípa bí a óo ti ṣe fún ara wa ní ìwúrí láti ní ìfẹ́ ati láti ṣe iṣẹ́ rere.

Ka pipe ipin Heberu 10

Wo Heberu 10:24 ni o tọ