Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 10:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á súnmọ́ ọ̀dọ̀ rẹ̀ pẹlu òtítọ́ ọkàn ati igbagbọ tí ó kún, kí á fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wẹ ọkàn wa mọ́, kí ó wẹ ẹ̀rí-ọkàn burúkú wa nù, kí á fi omi mímọ́ wẹ ara wa.

Ka pipe ipin Heberu 10

Wo Heberu 10:22 ni o tọ