Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí eniyan tií ká aṣọ ni ìwọ óo ká wọn.Gẹ́gẹ́ bí aṣọ, a óo pààrọ̀ wọn.Ṣugbọn ní tìrẹ, bákan náà ni o wà.Kò sí òpin sí iye ọdún rẹ.”

Ka pipe ipin Heberu 1

Wo Heberu 1:12 ni o tọ